Àfojúsùn isẹ́ yìí ni láti ṣe àkójọpọ̀ àti àkọsílẹ̀ àwọn ìtàn àti ọ̀rọ̀ ẹ̀rí láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré Yorùbá. Ní ìbámu pẹ̀lú ètò tí à ń tẹ̀lé, a yóò máa ṣe àgbéjáde àwọn isẹ́ ìtàn wọ̀nyí bí wọ́n bá ṣe ń tẹ̀ wá lọ́wọ́. A yóò ṣe àgbàwọlé àti àmúlò ìrànlọ́wọ́ tàbí ìdáhùn tí ẹ bá fi ṣọwọ́ sí wa. Fún àwọn ìfọ̀rọ̀wérọ̀ àkọ́kọ́, Rasaq Malik, Oǹkewì, ọmọ bíbí ìlú Nàìjíríà, káàkiri ẹkùn gúúsù-ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà. Ó bá àwọn àgbà òṣèré bíi Bàbá Lere Paimo àti Alàgbà Musiliu Dasofunjo sọ̀rọ̀ nípa isẹ́ fíìmù Yorùbá ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Trans: The Yorùbá Veterans Oral History Project aims to collect and document here oral accounts and testimonies of elders and seniors in the Yorùbá filmmaking segment of Nollywood. Like the main project itself, much of the work is ongoing and contents are being uploaded as they become available. Contributions and feedback are welcomed. In the first set of interviews, Nigerian poet, Rasaq Malik travelled around the south-west of Nigeria, and sat down with several veterans of Yorùbá Nollywood, including bàbá Lere Paimo and Musiliu Dasofunjo, to discuss the Yorùbá movie industry in the country.
Mistura Asunmo (Ọdún tí wọ́n bẹ̀rẹ̀:1969)
-
Ẹgbẹ́: Ọ̀súndáró Concert party
Adedeji Aderemi [(Olofa ina),Ọdún tí wọ́n bẹ̀rẹ̀: 1970]
-
Ẹgbẹ́: Oyetunji Concert party
Kareem Adepoju [(Baba Wande),Ọdún tí wọ́n bẹ̀rẹ̀:N/A]
- Ẹgbẹ́: Oyin Adejobi Group.
Lere Paimo, Ọdún tí wọ́n bẹ̀rẹ̀: N/A
-
Ẹgbẹ́: Oyin Adejobi/Dúró Ladipo Theatres
Fatai Adetayo (Lalude, Ọdún tí wọ́n bẹ̀rẹ̀: 1970)
-
Ẹgbẹ́: Oluwole Concert party (Ọdún mẹ́rin)/Ademola Theatre Group