HomeỌ̀rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré YorùbáLere Paimo

Lere Paimo

Ọdún tí wọ́n bẹ̀rẹ̀: N/A 

Ọ̀rọ̀ ṣókí: Ọfà tí mo lò nínú Ògbórí Ẹlẹ́mọ̀ṣọ́, ọfà tí bàbá bàbá mi fi jagun ni... Àìpé yìí ni àwọn kan ní wọ́n fẹ́ ṣe Museum ní UI, Aláròyé, ni wọ́n wá gba ọfà òhún tí wón wá kò o lọ. Mo ní inú ilé ni àwa ti ń wò ó, tí wọ́n bá kó o sí ibi ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn yóò ti máa ríi, tí orúkọ wá sì wà níbẹ̀, ó tún bu iyì kún àṣà Yorùbá náà ni" (ọjọ́ ìfọ̀rọ̀wérọ̀: August 28, 2020).

Trans: The bow and arrows I used in "Ògbórí Ẹlẹ́mọ̀ṣọ́' were the same ones my grandfather, a warrior, used. A group, Alaroye, recently came to inform me of their desire to have the weapon in a museum they were setting up at the University of Ibadan. I let them have it. I thought that the museum option would be beneficial to both the donor and visitors to the museum. I also thought about how that option can help promote Yoruba culture. 

Ẹgbẹ́: Oyin Adejobi/Dúró Ladipo Theatres