Adedeji Aderemi
Ọdún tí wọ́n bẹ̀rẹ̀: 1970
Ọ̀rọ̀ ṣókí: bí a bá fẹ́ ṣeré nílé oní ìnáwó, bóyá oníyàwó àbí ilé oní ìkómọ, à á ṣẹ̀ṣẹ̀ create stage, à á ṣẹ̀ṣẹ̀ to set. Set yìí-- àwọn awúsá ń pe nǹkan kan ní saana, koríko tí wọ́n hun, tí ó dà bíi ẹní pàkìtì. A yóò to bíi méjì, mẹta rẹ pọ̀, tí a ó fi to stage, tí ó jẹ́ wípé àárín rẹ̀ ni a ó ti máa ṣeré, tí a ó kojú sí àwọn audience. A yóò fi orí rù ú ni, kò sí owó tí a ó fi gbe sí mọ́tò (ọjọ́ ìfọ̀rọ̀wérọ̀: August 26, 2020).
Trans: We had to set up a stage everywhere we went to stage a play. It could be at a wedding or naming ceremony. To create the set, we used something the Hausa call saana. It is mat-like. We used about two or three. We had to carry our props around on our heads since we couldn't afford to pay for transportation.
Ẹgbẹ́: Oyetunji Concert party