Mistura Asunmo
Ọdún tí wọ́n bẹ̀rẹ̀:1969
Ọ̀rọ̀ ṣókí: Iṣẹ́ tíátà jẹ́ iṣẹ́ tí ó lágbára, ẹ kò leè mú iṣẹ́ míì mọ́ ọ. Nítorí mò ń ta oúnjẹ tẹ́lẹ̀. Ǹjẹ́ o jẹ́ mọ̀ wípé tíátà, ìgbà tí mo ṣe 'ìkà ni ọmọ ejò' hun, ni ó gba oúnjẹ ní ọwọ́ mi. Lagos Garage ni mo ti ń ta oúnjẹ ní Ìwó Road. Bí èèyàn yóò ṣe pé bòmí nìyí. Ṣùgbọ́n nígbà tí ìràwọ̀ ti jáde, bí a kò ṣe lè tá oúnjẹ mọ́ nìyẹn, tí ó jẹ́ pé location ni (ọjọ́ ìfọ̀rọ̀wérọ̀: 6th August, 2020).
Trans: Acting is quite demanding; you can't have another job. I used to be a food vendor but had to stop after I acted in the 'ìkà ni ọmọ ejò' movie; my acting career became very demanding. My stall was at the Lagos motor park, Iwo road. I enjoyed good patronage but had to stop when I became a sought-after actress. I was moving from one location to another.
Ẹgbẹ́: Ọ̀súndáró Concert party