HomeỌ̀rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré YorùbáFatai Adetayo

Fatai Adetayo

Ọdún tí wọ́n bẹ̀rẹ̀: 1970

Ọ̀rọ̀ ṣókí: Ìgbésí ayé gan-an, níbi tí a ti fi ẹsẹ̀ múlẹ̀ dáadáa, orí stage ni. Eré orí ìtàgé gangan ni ó fún wa ní ẹ̀kọ́ tí ó tóbi jù tí a fi ń ṣe fíìmù (ọjọ́ ìfọ̀rọ̀wérọ̀: August 8, 2020).

Trans: The stage helped us get established in life. It was also the stage play that prepared us for filmmaking.

Ẹgbẹ́: Oluwole Concert party (Ọdún mẹ́rin)/Ademola Theatre Group